Ìròyìn Amẹrika àti Israel pa ọwọ́ pọ̀ ju ọ̀pọ̀ àdó olóró sí Iran Feb 28, 2026 Asejere Oguntoye Mariam Ijọba ilẹ Amẹrika ati orilẹede Israel ti pawọ pọ lati ju ado oloro si Iran. Awọn…
Ìròyìn Akọrin Fuji, Shanko Rasheed pàdánù àkọ́bí ọmọ rẹ̀, Jamal Feb 27, 2026 Asejere Oguntoye Mariam Gbajúmọ̀ olórin Fuji, Atanda Adekunle Rasheed tí ọ̀pọ̀ mọ̀ sí Shanko Rasheed ti pàdánù àkọ́bí ọmọ rẹ̀,…
Ìròyìn Àjọ INEC kéde ọjọ́ tuntun fún ìbò Gómìnà ìpínlẹ̀ Osun Feb 27, 2026 Asejere Oguntoye Mariam Ajọ eleto idibo lorilẹede Naijiria (INEC) ti mu ọjọ tuntun fun eto idibo aarẹ, gomina ati ile…
Ìròyìn Fintiri ti de si APC, ko si gba ti Atiku oni gba Dubai lọ – Onanuga Feb 27, 2026 Asejere Zainab Omowunmi Oludamọran pataki fun aarẹ orile-ede Naijiria lori ọrọ ìròyìn, Bayo Onanuga ti sọ di mimọ pe orire…
Ìròyìn Sanwo-Olu ṣe ikilọ aloju ẹrọ igbalode nibi akanṣe ipade “Lagos Boy Child Feb 27, 2026 Asejere Oguntoye Mariam Ìyàwó Gomina Ìpínlẹ̀ Èkó, arabirin. Ibijoke Sanwo-Olu, ti tún fi ìtẹnumọ́ re hàn lórí ìtọ́sọ́nà àti ìdàgbàsókè…
Ìròyìn Makinde, Kwankwaso ṣe ipade ikọkọ ni ibadan Feb 26, 2026 Asejere Oguntoye Mariam Gomina Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde, ti ṣe ipade ikọkọ pẹ̀lú adarí àgbà ẹgbẹ́ New Nigeria People’s Party…
Ìròyìn Tunji Disu di adelé Ọ̀gá Ọlọ́pàá Naijiria tuntun lẹ́yìn tí Kayode Egbetokun kọ̀wé fipò sílẹ̀ Feb 25, 2026 Asejere Oguntoye Mariam Tunji Disu ti di adele ọga ọlọpaa Naijiria tuntun lẹyin ti Kayode Egbetokun kọwe fi ipo silẹ.…
Ìròyìn Tinubu gb’ọpa aṣẹ fun Disu, ọga ọlọ́pàá patapata Feb 25, 2026 Asejere Zainab Omowunmi Ààrẹ orile-ede Naijiria, Bola Ahmed Tinubu ti gbe ọ̀pá aṣẹ ọga agba pátápátá fun ileeṣẹ ọlọọpa le…
Ìròyìn Keyamo ṣe abẹwo si Terminal ti Ina bajẹ ni Papakọ ofurufu Murtala Muhammed Feb 25, 2026 Asejere Oguntoye Mariam Ana Ọjọ Iṣẹgun yii ni minista fun eto Ofurufu, Festus Keyamo ṣe abẹwo si Terminal ìyẹn ile ibẹwo…
Ìròyìn Bamidele Okemesi di oloogbe Feb 25, 2026 Asejere Zainab Omowunmi Gbajugbaja oṣere adẹrin poṣonu nni, Bamidele Oluwatope Saint ti ọpọlọpọ awọn eniyan mọ si Okemesi lo…