Ẹgbẹ Egba For Yayi Women Forum ṣe Adura Onigbagbọ ọlọjọ mẹrinla fun Sẹnetọ Yayi
Zainab Omowunmi Ẹgbẹ Egba For Yayi Women Forum ti wọn jẹ ẹgbẹ awọn olólùfẹ́ Yayi labẹ asia ẹgbẹ oṣelu…
Makinde ṣe bẹbẹ nipinlẹ Oyo, onírúurú ìṣẹ àkànṣe lo ti gbé ṣe
Zainab Omowunmi Awọn ara ipinlẹ Oyo ti gbe osuba kare lai fun gomina ipinlẹ naa, Seyi Makinde fun…
Ẹgbẹ oṣelu PDP o ku o, digbi lo duro – Oyinlola
Zainab Omowunmi Gomina tẹ́lẹ̀ ri nipinlẹ Osun, Olagunsoye Oyinlola ti sọ di mimọ pe ko si ohun to le…
Ọwọ́ ọlọ́pàá Kwara tẹ afurasí ajínigbé tó múra bíi oníbárà
Oguntoye Mariam Ọwọ sinku awọn ọlọpaa ipinlẹ Kwara ti tẹ afurasi ajinigbe kan ti o n ṣe bi ẹni…
Sanwó-Olú ṣèfillọ́lẹ̀ àwọn aṣojú káàkiri ìjọba ìbílẹ̀ l’Ékòó
Oguntoye Mariam Goomina ipinlẹ Eko, Babajide Sanwo-Olu ati igbakeji rẹ Dọkita Ọbafẹmi Hamzat, lanaa Ọjọru Wẹsidee, ṣefilọlẹ awọn aṣoju ti…
Ijọba Eko Pín Ilé Ìtajà Fún Àwọn Oníṣòwò Ní Ọjà Alaba Tuntun
Oguntoye Mariam Awọn ọlọja Alaba Rago fi idunnu wọn han si ijọba ipinlẹ Eko bi wọn ṣe gba…
‘A maá lo ẹ̀rọ ayélujára fún èsì ìdìbò, ẹ má jà wá lólè’
Oguntoye Mariam Awọn olufẹhonuhan ti wọn pejọ si Ile igbimọ aṣofin agba orilẹede Naijiria ti ke gbajare si awọn…
Ń kò padà sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin, ipò gómìnà ìpínlẹ́ Ogun ni ojú mi wá
Oguntoye Mariam Ọmọ ile igbimọ aṣofin nigba kan ri, Ọjọgbọn Iyabo Obasanjo ti wọgile erongba awọn kan ti wọn…
Awọn ajinigbe ilu Osun ti beere fun owo ọgọọrun miliọnu naira N100m
Zainab Omowunmi Awọn ajinigbe ti wọn gbé eyan meji ni ilu Ora Igbomina, nipinlẹ Osun ti bere fun owo…
Tinubu seleri lati bori aisi eto abo to peye ati Jagidijagan ni orile-ede Naijiria
Zainab Omowunmi Ìṣàkóso mi yoo ri daaju pé eto abo to peye wa ni orile-ede Naijiria ti ọ̀rọ̀ ìjinigbe ati…










