
Awọn aṣoju Aarẹ Muhammadu Buhari ti ṣabẹwo sile Aṣiwaju Bọla Tinubu. Ile rẹ to wa ni Bourdillon ni Ikoyi l’Ekoo ni wọn ti lọọ ba a.
Adari awọn oṣiṣẹ Aarẹ Muhammadu Buhari; Ọjọgbọn Ibrahim Agboọla Gambari lo ṣaaju ikọ naa ti awọn minisita to jẹ ọmọ ilẹ Yoruba naa wa nibẹ.
Ohun taa gbọ ni pe awọn aṣoju naa lọọ ṣe ikini ibanikẹdun si Tinubu, nitori awọn ajalu ati ileeṣẹ rẹ tawọn janduku ba jẹ lasiko iwọde ENDSARS.
Lẹyin ti awọn ikọ naa pari ipade wọn pẹlu awọn ọba alaye ilẹ Yoruba, ati awọn gomina ilẹ Yoruba ni wọn gba ile agba oloṣelu naa lọ.
Titi di bi a ti n kọ iroyin yii, a o ti i rẹni sọ pato ohun to ṣẹlẹ ninu ipade naa fun wa, ju pe wọn waa ki Tinubu.

I love writing historical books. I enjoy the research and learning so much more about a specific event or era. Eachelle Pernell Weinshienk
Hey very nice web site!! Man .. Beautiful .. Wonderful .. Dionis Adler Kerekes
Hi to all, how is all, I think every one is getting more from this web site, and your views are fastidious designed for new viewers. Karisa Ricki Timofei
Thanks, you may reach us on asejerenewsroom@yahoo.com
Thanks
I conceive this site contains some really fantastic information for everyone :D. Lea Raimondo Maryly
Enjoyed every bit of your post. Really thank you! Awesome. Isis Berny Artur
Hello there. I found your website by means of Google even as looking for a comparable topic, your site got here up. It seems good. I have bookmarked it in my google bookmarks to come back then. Briny Walt Haff