Aláàfin gbe oríyìn fún Ìgbó-Ọ̀rà lórí bí wọ́n ṣe gbé àṣà ọdún Ìbejì gáa
Zainab Omowunmi Aláàfin ilu Oyo, Oba Akeem Owoade ti gbe oṣuba kare lai fun àwọn ara ilu Igbo…
Gàrí àti omi ìdọ̀tí l’à mú ní àhamọ́ àwọn àjínigbé’ — Àgunbánirọ̀ sọ ohun tí ojú rẹ̀ rí
Zainab Omowunmi Ọ̀kan lára àwọn ọmọ àgunbánirọ̀ tí àwọn àjínigbé gbé nínú ìṣẹ̀lẹ̀ ìjígbé ìpínlẹ̀ Imo ti sọ…
Awọn oniṣẹ-ọwọ, oniṣowo atawọn ọlọja fẹẹ bẹrẹ ipolongo fun Tinubu ati Hamzat
Ẹgbẹ́ àwọn oníṣòwò àti àwọn tó ń ta ọjà ní Ìpínlẹ̀ Èkó, lábẹ́ àjọ Renewed Hope Ambassadors (RHA), ti kéde…
Ọkan mi balẹ lori ibi taa gbe ipagọ awọn obinrin COWLSO de l’Ekoo – Aya Sanwo-Olu
Ìyàwó Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, Dókítà Ibijoke Sanwo-Olu, ti sọ pé inú òun dùn, òun sì ní ìtẹ́lọ́rùn pẹ̀lú ipa tí…
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ Halilu to fipá fún ọmọdébìnrin ọmọ ọdún méjìlá loyún laÀbújá
Zainab Omowunmi Ileeṣẹ ọlọ́pàá ilu FCT ìyẹn Abuja ti sọ di mimọ pe àwọn ti fi ọwọ́ ofin mu…
Ajínigbe beèrè bílíọ̀nù kan náírà lórí àwọn àgunbánirọ̀ Ọ̀yọ́, wọ́n halẹ̀ láti pa wọ́n
Zainab Omowunmi Àwọn obi àwọn ọmọ agunbanirọ ògùn(20) ti wọn jigbe nipinlẹ Imo ti ke gbanjare sita. Wọn…
Mio ba Yayi ṣẹ jọ mọ, emi na fẹ ki Yewa di gómìnà – Rotham
Zainab Omowunmi Adijedupo gómìna nipinlẹ Ogun labẹ asia ẹgbẹ́ òṣèlú New Nigeria People’s Party, Akinbola Rotham ti ṣe alaye…
D’Banj ta Olajengbesi lọ́rẹ ẹ̀bùn ọkọ̀ fún ìpólongo ìbò rẹ̀
Zainab Omowunmi Gbajugbaja olorin takasufe ọmọ orile-ede Naijiria nni, Dapo Oyebanjo, ti ọpọ èyàn mọ si D’Banj, ti fi …
Àṣá wa ni ṣunkẹrẹ fakẹrẹ ọkọ̀ niluu Eko, kii ṣe aarun
Zainab Omowunmi Ẹni to jẹ igbakeji gómìnà nipinlẹ Eko to tun jẹ adijedupo si ipo gómìnà labẹ àsíá ẹgbẹ́…
Sanwo-Olu gboriyin fun Ileewe St. Gregory’s, bẹẹ ni wọ́n f’ami ẹ̀yẹ da Agoro, Disu lọ́la
Ìpínlẹ̀ Èkó, Babajide Olusola Sanwo-Olu, ti gbóríyìn fún ileewe St. Gregory’s College fún ipa tí ilé ẹ̀kọ́ náà ti ń…










