Ìròyìn Ìjọba Ogun fọwọ si ọjọ isinmi ọsẹ ati owo ọkọ #10,000 fun awọn oṣiṣẹ Apr 16, 2026 Asejere Zainab Omowunmi Lori ọrọ ọwọn gogo owo epo bẹẹntiro, ìjọba ipinlẹ Ogun labẹ asia Omoọba Dapo Abiodun ti yanda isinmi…
Ìròyìn Lẹyin idije ọdún 2027,mi o ni du ipo aarẹ orile-ede Naijiria mọ – Atiku Abubakar Apr 16, 2026 Asejere Zainab Omowunmi Igbakeji aarẹ nigbakan ri ni orile-ede Naijiria to tun jẹ adijedupo aarẹ ọdún 2023 labẹ asia ẹgbẹ…
Ìròyìn Omoọba ki Yayi ku oriire lori Yiyan rẹ gẹgẹ bi Oludibo apapọ fun ipo gomina Ogun Apr 14, 2026 Asejere Zainab Omowunmi Adijedupo sile gbimọ aṣofin agba fun Ijọba ibilẹ Abeokuta South nipinlẹ Ogun, Omoọba Sheriff Adeola Olabode…
Ìròyìn Mo yanda ipo gomina ipinlẹ Ogun fun Yayi, Iyabo Obasanjo Apr 14, 2026 Asejere Zainab Omowunmi Ọmọ aarẹ orile-ede Naijiria tẹlẹri to tun jẹ adijedupo gomina nipinlẹ Ogun labẹ asia…
Ìròyìn Trump kéde ìgbésẹ̀ tó kàn lẹ́yìn tí ìjíròrò pẹ̀lú Iran forí sánpọ́n Apr 13, 2026 Asejere Oguntoye Mariam Lẹ́yìn ìjíròrò láàárín Amẹ́ríkà àti Iran forí sánpọ́n ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, Ààrẹ Amẹ́ríkà, Donald Trump ti kéde…
Ìròyìn Makinde, Olubadan fèsì lórí ẹ̀sùn Fayose pé ìjọba Oyo fẹ́ rọ Olubadan Ladoja lóyè Apr 13, 2026 Asejere Oguntoye Mariam Gomina tẹ́lẹ̀ ni ìpínlẹ̀ Ekiti, Ayodele Fayoṣe, ke sita nirọlẹ ọjọ Aiku ana, pe Gomina Makinde n…
Ìròyìn Ìjọba yóò máa gba ìwé ìrìnnà lọ́wọ́ àwọn tó bá ní àwọn kì í ṣe ọmọ Naijiria mọ́ Apr 13, 2026 Asejere Oguntoye Mariam Minisita ọrọ abẹle, Olubunmi Tunji-Ojo, ti paṣẹ pe kawọn ileeṣẹ to n ri si iwọle-jade (Nigeria Immigration…
Ìròyìn Ko si nnkan to wu mi ju’po gomina Ogun lo – Iyabo Obasanjo Apr 12, 2026 Asejere Ọmọ aarẹ orile-ede Naijiria nígbà kan ri to tun ti fi gba kan ri jẹ sẹnetọ laarin…
Ìròyìn Ìdílé oyè fún Gómìnà Adeleke ní gbèdéke ọjọ́ méje láti rọ Apetumodu tó ń ṣẹ̀wọ̀n l’Ámẹ́ríkà lóyè Apr 11, 2026 Asejere Oguntoye Mariam Idile oye meji pẹlawọn afọbajẹ ni ilu Ipetumodu ni ipinlẹ Ọṣun, ti fun gomina ipinlẹ naa, Ademọla…
Ìròyìn Wo bí o ṣe lè wo, tàbí ṣe àtẹ̀jáde ìwé atọ́nà pélébé fún ìdánwò Jamb UTME Apr 11, 2026 Asejere Oguntoye Mariam Ajọ to n ṣe aayan idanwo aṣewọle si ile ẹkọ giga gbogbo lorilẹede Naijiria JAMB ti…