Omobinrin osere tiata kan ti oruko re n je Ruth Eze ti so o di mimo pe oun ko setan ati ko oko oun sile nitori agbere rara.
Ninu iforowero ti omobinrin naa se pelu awon oniroyin lopin ose to koja yii, o so pe baba oun ti kilo foun tele pe gbogbo okunrin lo ni oju kokoro okunrin.

O ni, gbogbo okunrin lo maa n se agbere, bi awon pasito ti n se lawon alufaa naa n se, sugbon omobinrin naa ni okunrin oninufufu ati onija nikan loun ko le ba gbele.

Ko si okunrin to le se olooto si iyawo re, ibe le ti maa ri okunrin to n gbaradi lati segbeyawo lola, to tun loo ba obinrin mi in sun, nitori naa ko bewu de rara fun emi o, lomobinrin naa so.

 

By Asejere

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Follow by Email
WhatsApp