Gbajumọ oṣere tiata Yoruba, iyẹn obinrin torukọ rẹ n jẹ Kẹmi Afọlabi la tun gbọ pe oun naa ti kọle olowo nla ninu ọdun tuntun.
Abiọla Adebayọ, toun naa jẹ oṣere tiata lo gbe iroyin naa sori ẹrọ ayelujara Instagram.
Kẹmi naa ti pẹlu awọn bii Funkẹ Akindele, Iyabọ Ojo, Mercy Aigbe, ati Toyin Abraham ti wọn ti nile tiwọn.

By Asejere

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Follow by Email
WhatsApp