Asiwaju Bola Ahmed Tinubu, asoju egbe oselu APC ninu ibo Aare ti wa niluu Abeokuta nipinle Ogun. Ipade lo se pelu Aare Olusegun Obasanjo.

Ohun taa gbo ni pe ipade pelu Obasanjo je okan ninu awon ipade idakonko ti Tinubu n se pelu awon alenuloro ko too di asiko ibo odun to n bo.

Opo awon oba alade ati oloselu ni Tinubu ti sepade pelu ko too di asiko yii.

Sugbon ko lanfaani ati fojukoju pelu Obasanjo latigba naa.

By Asejere

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Follow by Email
WhatsApp