Ìròyìn AWORAN: Alaafin ati Oniru foju kan ara wọn Jan 29, 2021 Asejere Alaafin Ọyọ, Iku baba Yeye, Ọba Lamidi Adeyẹmi III, ṣabẹwo si aafin Oniru tilẹ Iru, Ọba Ọmọgbọlahan Lawal, Abisogun II…
Ìròyìn Ṣọra fawọn oloṣelu o, Ọọni kilọ fun Sunday Igboho Jan 28, 2021 Asejere Ọọni Ile Ifẹ, Babatunde Ogunwusi, Ọjaja II, ti kilọ fun ajijagbara ilẹ Yoruba nni, Sunday Igboho, pe ko ṣọra fun…
Ìròyìn Debọla ọmọ Gbenga Daniel sọ pe, feeki lo pọ ju ninu awọn wolii to n gbadura fun oun Jan 28, 2021 Asejere Debola Daniel, ọmọ gomina ana nipinlẹ Ogun, iyẹn Gbenga Daniel ti fi aidunnu rẹ han si pupọ ninu awọn wolii…
Ìròyìn Ipinlẹ Ogun ni mo n gbeja lọ bayii – Sunday Igboho Jan 28, 2021 Asejere Ajijagbara ilẹ Yoruba tirawọ rẹ n tan lọwọ yii, Sunday Igboho, tawọn eeyan tun mọ si Igboho Ooṣa ti sọ…
Ìròyìn Ọ̀rọ̀ tó ń lọ Loootọ ni Tinubu fun mi ni miliọnu meji naira fowo mọto lọjọ taa pade, ṣugbọn … – Sunday Igboho Jan 26, 2021 Asejere Oloye Sunday Adeyẹmọ, ti gbogbo eeyan mọ si Sunday Igboho ti sọ ọ di mimo pe loootọ ni Aṣiwaju Bọla…
Ìròyìn Buhari yọ ọga awọn ologun ilẹ wa bii jiga Jan 26, 2021 Asejere Aarẹ Muhammadu Buhari ti yọ adari gbogbo awọn ologun ilẹ wa, bẹẹ lo si ti fi awọn ẹlomii rọpo wọn.Awọn…
Ìròyìn Lojiji, ina ṣẹyọ nile Sunday Igboho Jan 26, 2021 Asejere Iroyin to n tẹ wa lọwọ ti fihan pe ṣadeede ni ina ṣẹyọ nile Sunday Adeyẹmọ, tawọn eeyan n pe…
Ìròyìn Awọn Fulani daran-daran bẹbẹ, wọn lawọn ko ni ṣe bẹẹ mọ Jan 26, 2021 Asejere OIori awọn fulani daran-daran to wa nilẹ Yoruba, Alaaji Kirowa Ardo Zuru, ti rawọ ẹbẹ si awọn gomina ilẹ Yoruba,…
Ìròyìn Ọ̀rọ̀ tó ń lọ Awọn gomina fofin de awọn Fulani daran-daran nilẹ Yoruba Jan 26, 2021 Asejere Awọn gomina ilẹ Yoruba ti fẹnu ko pe fifi maaluu jẹ oko lalẹ tabi loru ti di eewọ kaakiri awọn…
Ìròyìn Isọkusọ ni Bisoye Oshodi n sọ, irọ lo n pa – Sẹnetọ Abiru Jan 25, 2021 Asejere Sam AkinroleỌmọleegbimọ aṣofin to n ṣoju ẹkun idibo ila oorun Eko, iyen Lagos East, Sẹnetọ Tokunbọ Abiru ti ṣapejuwe ọrọ…